Rom 4:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NJẸ kili awa o ha wipe Abrahamu, baba wa nipa ti ara, ri?

2. Nitori bi a ba da Abrahamu lare nipa iṣẹ, o ni ohun iṣogo; ṣugbọn kì iṣe niwaju Ọlọrun.

Rom 4