O. Daf 3:6-8 Yorùbá Bibeli (YCE)

6. Emi kì yio bẹ̀ru ọ̀pọlọpọ enia, ti nwọn rọ̀gba yi mi ka.

7. Dide Oluwa; gbà mi, Ọlọrun mi: nitori iwọ li o lù gbogbo awọn ọta mi li egungun ẹrẹkẹ; iwọ si ká ehin awọn enia buburu.

8. Ti Oluwa ni igbala: ibukún rẹ si mbẹ lara awọn enia rẹ.

O. Daf 3