O. Daf 16:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ỌLỌRUN, pa mi mọ́: nitori iwọ ni mo gbẹkẹ mi le.

2. Ọkàn mi, iwọ ti wi fun Oluwa pe, Iwọ li Oluwa mi: emi kò ni ire kan lẹhin rẹ.

O. Daf 16