Neh 7:37-40 Yorùbá Bibeli (YCE) Awọn ọmọ Lodi, Hadidi, ati Ono, ọrindilẹgbẹrin o le ọkan. Awọn ọmọ Senaah ẹgbãji o di ãdọrin.