Neh 7:29-32 Yorùbá Bibeli (YCE)

29. Awọn ọkunrin Kiriat-jearimu, Kefira, ati Beeroti, ọtadilẹgbẹrin o le mẹta,

30. Awọn ọkunrin Rama ati Gaba, ẹgbẹta o le mọkanlelogun.

31. Awọn ọkunrin Mikmasi, mejilelọgọfa.

32. Awọn ọkunrin Beteli ati Ai, mẹtalelọgọfa.

Neh 7