Neh 12:16-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

16. Ti Iddo, Sekariah; ti Ginnetoni, Meṣullamu;

17. Ti Abijah, Sikri; ti Miniamini, ti Moadiah, Piltai:

18. Ti Bilga, Sammua; ti Ṣemaiah, Jehonatani;

19. Ati ti Joaribu, Mattenai; ti Jedaiah, Ussi;

20. Ti Sallai, Killai; ti Amoku, Eberi;

Neh 12