Mat 7:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ẹ máṣe dani li ẹjọ, ki a ma bà da nyin li ẹjọ.

2. Nitori irú idajọ ti ẹnyin ba ṣe, on ni a o si ṣe fun nyin; irú òṣuwọn ti ẹnyin ba fi wọ̀n, on li a o si fi wọ̀n fun nyin.

Mat 7