Lef 7:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. EYI si li ofin ẹbọ ẹbi: mimọ́ julọ ni.

2. Ni ibi ti nwọn gbé pa ẹbọ sisun ni ki nwọn ki o pa ẹbọ ẹbi: ki o si fi ẹ̀jẹ rẹ̀ wọ́n ori pẹpẹ yiká.

Lef 7