Joh 16:8-10 Yorùbá Bibeli (YCE)

8. Nigbati on ba si de, yio fi òye yé araiye niti ẹ̀ṣẹ, ati niti ododo, ati niti idajọ:

9. Niti ẹ̀ṣẹ, nitoriti nwọn kò gbà mi gbọ́;

10. Niti ododo, nitoriti emi nlọ sọdọ Baba, ẹnyin kò si ri mi mọ́;

Joh 16