Jer 5:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ẹrìn kiri la ita Jerusalemu ja, ki ẹ si wò nisisiyi, ki ẹ si mọ̀, ki ẹ si wakiri nibi gbigbòro rẹ̀, bi ẹ ba lè ri ẹnikan, bi ẹnikan wà ti nṣe idajọ, ti o nwá otitọ; emi o si dari ji i.

2. Bi nwọn ba si wipe, Oluwa mbẹ; sibẹ nwọn bura eke.

Jer 5