Jak 2:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) ẸNYIN ará mi, ẹ máṣe fi iṣãju enia dì igbagbọ́ Oluwa wa Jesu Kristi Oluwa ogo mu. Nitori bi ọkunrin kan ba