Isa 24:9-11 Yorùbá Bibeli (YCE)

9. Nwọn kì yio fi orin mu ọti-waini mọ́; ọti-lile yio koro fun awọn ti nmu u.

10. A wó ilu rúdurudu palẹ: olukuluku ile li a se, ki ẹnikan má bà wọle.

11. Igbe fun ọti-waini mbẹ ni igboro; gbogbo ayọ̀ ṣú òkunkun, aríya ilẹ na lọ.

Isa 24