Isa 13:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ọ̀RỌ-ìmọ niti Babiloni ti Isaiah ọmọ Amosi ri.

2. Ẹ gbe ọpágun soke lori oke giga, ẹ kọ si wọn, ẹ juwọ, ki nwọn ba le lọ sinu ẹnu-odi awọn ọlọla.

Isa 13