Ifi 2:27-29 Yorùbá Bibeli (YCE)

27. On o si mã fi ọpá irin ṣe akoso wọn; bi ã ti ifọ́ ohun elo amọ̀koko li a o fọ́ wọn tũtu: bi emi pẹlu ti gba lati ọdọ Baba mi.

28. Emi o si fi irawọ owurọ̀ fun u.

29. Ẹniti o ba li eti, ki o gbọ́ ohun ti Ẹmi nsọ fun awọn ijọ.

Ifi 2