Iṣe Apo 26:31-32 Yorùbá Bibeli (YCE)

31. Nigbati nwọn lọ si apakan, nwọn ba ara wọn sọ pe, ọkunrin yi kò ṣe nkankan ti o yẹ si ikú tabi si ẹ̀wọn.

32. Agrippa si wi fun Festu pe, A ba dá ọkunrin yi silẹ ibamaṣepe kò ti fi ọ̀ran rẹ̀ lọ Kesari.

Iṣe Apo 26