Iṣe Apo 12:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. LI akoko igbana ni Herodu ọba si nawọ́ rẹ̀ lati pọn awọn kan loju ninu ijọ.

2. O si fi idà pa Jakọbu arakunrin Johanu.

Iṣe Apo 12