Iṣe Apo 10:12-14 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Ninu rẹ̀ li olorijorí ẹranko ẹlẹsẹ mẹrin wà, ati ohun ti nrakò li aiye ati ẹiyẹ oju ọrun.

13. Ohùn kan si fọ̀ si i pe, Dide, Peteru; mã pa ki o si mã jẹ.

14. Ṣugbọn Peteru dahùn pe, Agbẹdọ, Oluwa; nitori emi kò jẹ ohun èwọ ati alaimọ́ kan ri.

Iṣe Apo 10