1. Tim 5:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. MÁṢE ba alàgba wi, ṣugbọn ki o mã gba a niyanju bi baba; awọn ọdọmọkunrin bi arakunrin;

2. Awọn àgba obinrin bi iya; awọn ọdọmọbirin bi arabinrin ninu ìwa mimọ́.

3. Bọ̀wọ fun awọn opó ti iṣe opó nitõtọ.

1. Tim 5