Hag 2:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. LI oṣù keje, li ọjọ kọkanlelogun oṣù na, ni ọ̀rọ Oluwa wá nipa ọwọ́ Hagai woli, wipe,

2. Sọ nisisiyi fun Serubbabeli ọmọ Ṣealtieli, bãlẹ Juda, ati fun Joṣua, ọmọ Josedeki, olori alufa, ati fun awọn enia iyokù pe,

Hag 2