Gẹn 40:21-23 Yorùbá Bibeli (YCE)

21. O si tun mú olori agbọti pada si ipò rẹ̀; on si fi ago lé Farao li ọwọ́:

22. Ṣugbọn olori alasè li o sorọ̀: bi Josefu ti tumọ̀ alá na fun wọn.

23. Ṣugbọn olori agbọti kò ranti Josefu, o gbagbe rẹ̀.

Gẹn 40