Gẹn 25:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ABRAHAMU si tun fẹ́ aya kan, orukọ rẹ̀ a ma jẹ Ketura.

2. O si bí Simrani, ati Jokṣani, ati Medani, ati Midiani, ati Iṣbaku, ati Ṣua fun u.

Gẹn 25