Gẹn 17:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBATI Abramu si di ẹni ọkandilọgọrun ọdún, OLUWA farahàn Abramu, o si wi fun u pe, Emi li Ọlọrun Olodumare; mã rìn niwaju mi, ki iwọ ki o si pé.

2. Emi o si ba ọ dá majẹmu mi, emi o si sọ ọ di pupọ̀ gidigidi.

Gẹn 17