Gẹn 11:17-19 Yorùbá Bibeli (YCE)

17. Eberi si wà ni irinwo ọdún o le ọgbọ̀n lẹhin igbati o bí Pelegi tan, o si bí ọmọkunrin ati ọmọbinrin.

18. Pelegi si wà li ọgbọ̀n ọdún, o si bì Reu:

19. Pelegi si wà ni igba ọdún o le mẹsan lẹhin igbati o bí Reu tan, o si bí ọmọkunrin ati ọmọbinrin.

Gẹn 11