Esr 2:53-55 Yorùbá Bibeli (YCE)

53. Awọn ọmọ Barkosi, awọn ọmọ Sisera, awọn ọmọ Tama,

54. Awọn ọmọ Nesia, awọn ọmọ Hatifa,

55. Awọn ọmọ awọn iranṣẹ Solomoni: awọn ọmọ Sotai, awọn ọmọ Sofereti, awọn ọmọ Peruda,

Esr 2