Esr 10:42-44 Yorùbá Bibeli (YCE) Ṣallumu, Amariah, ati Josefu. Ninu awọn ọmọ Nebo; Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Ṣebina, Jadau, ati Joeli, Benaiah.