Eks 24:17-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

17. Iwò ogo OLUWA dabi iná ajonirun li ori òke na li oju awọn ọmọ Israeli.

18. Mose si lọ sãrin awọsanma na, o sì gùn ori òke na: Mose si wà lori òke li ogoji ọsán ati ogoji oru.

Eks 24