Eks 21:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NJẸ wọnyi ni idajọ ti iwọ o gbekalẹ niwaju wọn.

2. Bi iwọ ba rà ọkunrin Heberu li ẹrú, ọdún mẹfa ni on o sìn: li ọdún keje yio si jade bi omnira lọfẹ.

Eks 21