Eks 12:49-51 Yorùbá Bibeli (YCE)

49. Ofin kan ni fun ibilẹ ati fun alejò ti o ṣe atipo ninu nyin.

50. Bẹ̃ni gbogbo awọn ọmọ Israeli ṣe; bi OLUWA ti fi aṣẹ fun Mose ati Aaroni, bẹ̃ni nwọn ṣe.

51. O si ṣe li ọjọ́ na gan, OLUWA mú awọn ọmọ Israeli jade kuro ni ilẹ Egipti, gẹgẹ bi ogun wọn.

Eks 12