Eks 1:1-4 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NJẸ orukọ awọn ọmọ Israeli, ti o wá si Egipti pẹlu Jakobu ni wọnyi; olukuluku pẹlu ile rẹ̀.

2. Reubeni, Simeoni, Lefi, ati Judah;

3. Issakari, Sebuluni, ati Benjamini;

4. Dani ati Naftali, Gadi ati Aṣeri.

Eks 1