Ẹk. Jer 3:57-60 Yorùbá Bibeli (YCE) Iwọ sunmọ itosi li ọjọ ti emi kigbe pè ọ: iwọ wipe: Má bẹ̀ru! Oluwa, iwọ ti gba ijà mi jà; iwọ