Tẹsalonika Kinni 4:17-18 BIBELI MIMỌ (BM)

17. A óo wá gbé àwa tí ó kù lẹ́yìn, tí a wà láàyè, lọ pẹlu wọn ninu awọsanma, láti lọ pàdé Oluwa ní òfuurufú, a óo sì máa wà lọ́dọ̀ Oluwa laelae.

18. Ẹ máa fi ọ̀rọ̀ wọnyi tu ara yín ninu.

Tẹsalonika Kinni 4