Samuẹli Kinni 30:29-31 BIBELI MIMỌ (BM)

29. ní Rakali, ní àwọn ìlú Jerameeli, àwọn ìlú Keni,

30. ní Homa, Boraṣani, ati ní Ataki,

31. ní Heburoni ati ní gbogbo ìlú tí Dafidi ati àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ ti rìn kiri.

Samuẹli Kinni 30