Samuẹli Kinni 24:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Nítorí náà, búra fún mi pé o kò ní pa ìdílé mi run lẹ́yìn mi, ati pé o kò ní pa orúkọ mi rẹ́ ní ìdílé baba mi.”

22. Dafidi bá búra fún Saulu.Saulu ati àwọn eniyan rẹ̀ pada sílé, Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ sì pada sí ibi tí wọ́n sá pamọ́ sí.

Samuẹli Kinni 24