Sakaraya 8:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA àwọn ọmọ ogun tún bá mi sọ̀rọ̀ pé Òun fẹ́ràn àwọn ará Sioni; nítorí náà ni inú òun ṣe ru