Orin Solomoni 5:14-15 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Ọwọ́ rẹ̀ dàbí ọ̀pá wúrà,tí a to ohun ọ̀ṣọ́ sí lára.Ara rẹ̀ dàbí eyín erin tí ń dántí a fi òkúta safire bò.

15. Ẹsẹ̀ rẹ̀ dàbí òpó alabasitatí a gbé ka orí ìtẹ́lẹ̀ wúrà.Ìrísí rẹ̀ dàbí òkè Lẹbanoni, ó rí gbọ̀ngbọ̀nràn bí igi Kedari.

Orin Solomoni 5