Orin Solomoni 1:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Háà, o mà dára o! Olùfẹ́ mi,o lẹ́wà gan-an ni.Ewéko tútù ni yóo jẹ́ ibùsùn wa.

17. Igi Kedari ni òpó ilé wa,igi firi sì ni ọ̀pá àjà ilé wa.

Orin Solomoni 1