Orin Dafidi 85:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, o fi ojurere wo ilẹ̀ rẹ;o dá ire Jakọbu pada.

2. O dárí àìdára àwọn eniyan rẹ jì wọ́n;o sì bo gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀.

3. O mú ìrúnú rẹ kúrò;o dáwọ́ ibinu gbígbóná rẹ dúró.

Orin Dafidi 85