Orin Dafidi 69:34-36 BIBELI MIMỌ (BM)

34. Jẹ́ kí ọ̀run ati ayé kí ó yìn ín,òkun ati gbogbo ohun tí ó ń rìn káàkiri ninu wọn.

35. Nítorí Ọlọrun yóo gba Sioni là;yóo sì tún àwọn ìlú Juda kọ́;àwọn iranṣẹ rẹ̀ yóo máa gbé inú rẹ̀,yóo sì di tiwọn.

36. Àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ rẹ̀ yóo jogún rẹ̀;àwọn tí ó fẹ́ràn orúkọ rẹ̀ yóo sì máa gbé inú rẹ̀.

Orin Dafidi 69