Orin Dafidi 58:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ǹjẹ́ ìpinnu tí ẹ̀ ń ṣe tọ̀nà, ẹ̀yin aláṣẹ? Ǹjẹ́ ẹ̀ ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan ní ọ̀nà ẹ̀tọ́?

2. Rárá o! Ibi ni ẹ̀ ń fi ọkàn yín rò,iṣẹ́ burúkú ni ẹ sì ń fi ọwọ́ yín ṣe láyé.

Orin Dafidi 58