Orin Dafidi 56:12-13 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Èmi óo san ẹ̀jẹ́ mi fún ọ, Ọlọrun;n óo sì mú ẹbọ ọpẹ́ wá fún ọ.

13. Nítorí pé o ti gba ẹ̀mí mi lọ́wọ́ ikú,o gbà mí, o kò jẹ́ kí n kọsẹ̀,kí n lè máa rìn níwájú Ọlọrunninu ìmọ́lẹ̀ ìyè.

Orin Dafidi 56