Orin Dafidi 54:6-7 BIBELI MIMỌ (BM)

6. N óo rú ẹbọ ọrẹ àtinúwá sí ọ,n óo máa yin orúkọ rẹ, OLUWA,nítorí pé ó dára bẹ́ẹ̀.

7. O ti yọ mí ninu gbogbo ìṣòro mi,mo sì ti fi ojú mi rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.

Orin Dafidi 54