Orin Dafidi 52:7-9 BIBELI MIMỌ (BM)

7. “Wo ẹni tí ó kọ̀, tí kò fi Ọlọrun ṣe ààbò rẹ̀,ṣugbọn ó gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ rẹ̀ tí ó pọ̀,ati jamba tí ó ń ta fún ẹlòmíràn.”

8. Ṣugbọn èmi dàbí igi olifi tútùtí ń dàgbà ninu ilé OLUWA,mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Ọlọrun tí kì í yẹ̀, lae ati laelae.

9. N óo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ títí lae,nítorí ohun tí o ṣe,n óo máa kéde orúkọ rẹ níwájú àwọn olùfọkànsìn rẹ,nítorí pé ó dára bẹ́ẹ̀.

Orin Dafidi 52