Orin Dafidi 5:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Fetí sí ọ̀rọ̀ mi, OLUWA;kíyèsí ìmí ẹ̀dùn mi.

2. Fetí sí igbe mi,Ọba mi ati Ọlọrun mi,nítorí ìwọ ni mò ń gbadura sí.

Orin Dafidi 5