Orin Dafidi 48:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA tóbi, ó sì yẹ kí á máa yìn ín lọpọlọpọní ìlú Ọlọrun wa.

2. Òkè mímọ́ rẹ̀, tí ó ga, tí ó sì lẹ́wà,ni ayọ̀ gbogbo ayé.Òkè Sioni, ní àríwá, lọ́nà jíjìn réré,ìlú ọba ńlá.

3. Ninu ilé ìṣọ́ ìlú náà, Ọlọrun ti fi ara rẹ̀ hàn bí ibi ìsádi.

Orin Dafidi 48