Orin Dafidi 46:10-11 BIBELI MIMỌ (BM)

10. “Ẹ dúró jẹ́ẹ́, kí ẹ sì mọ̀ pé èmi ni Ọlọrun.A gbé mi ga láàrin àwọn orílẹ̀-èdè,a gbé mi ga ní ayé.”

11. OLUWA àwọn ọmọ ogun wà pẹlu wa,Ọlọrun Jakọbu ni ààbò wa.

Orin Dafidi 46