6. Ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọkàn mi,nítorí náà mo ranti rẹláti òkè Herimoni,ati láti òkè Misari, wá sí agbègbè odò Jọdani,
7. ìbànújẹ́ ń já lura wọn,ìdààmú sì ń dà gììrì,wọ́n bò mí mọ́lẹ̀ bí ìgbì omi òkun.
8. Ní ọ̀sán, OLUWA fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ hàn,ní òru, orin rẹ̀ gba ẹnu mi,àní, adura sí Ọlọrun ìyè mi.