Orin Dafidi 40:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Sùúrù ni mo fi dúró de OLUWA,ó dẹ etí sí mi, ó sì gbọ́ igbe mi.

2. Ó fà mí jáde láti inú ọ̀gbun ìparun,láti inú kòtò tí ó kún fún ẹrọ̀fọ̀;ó gbé mi kalẹ̀ lórí àpáta,ó sì fi ẹsẹ̀ mi tẹlẹ̀.

Orin Dafidi 40