Orin Dafidi 33:20-22 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Ọkàn wa ní ìrètí lọ́dọ̀ OLUWA;òun ni olùrànlọ́wọ́ ati ààbò wa.

21. A láyọ̀ ninu rẹ̀,nítorí pé a gbẹ́kẹ̀lé orúkọ mímọ́ rẹ̀.

22. OLUWA, jẹ́ kí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ wà lórí wabí a ti gbẹ́kẹ̀lé ọ.

Orin Dafidi 33