Orin Dafidi 20:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA óo dá ọ lóhùn ní ọjọ́ ìpọ́njú,orúkọ Ọlọrun Jakọbu óo dáàbò bò ọ́.

2. Yóo rán olùrànlọ́wọ́ sí ọ láti ilé mímọ́ rẹ̀ wá,yóo sì tì ọ́ lẹ́yìn láti Sioni wá.

3. Yóo ranti gbogbo ẹbọ ọrẹ rẹ,yóo sì gba ẹbọ sísun rẹ.

Orin Dafidi 20