Orin Dafidi 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Kí ló dé tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń bínú fùfùtí àwọn eniyan ń gbìmọ̀ asán?

2. Àwọn ọba ayé kó ara wọn jọ,àwọn ìjòyè gbìmọ̀ pọ̀,wọ́n dojú kọ OLUWA ati àyànfẹ́ rẹ̀.

Orin Dafidi 2